Badagry Division
Badagry Division jẹ́ ilé jẹ́ ilé ìgbìmọ̀ fún ìṣètò Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà.
Ìtàn nípa rẹ̀
àtúnṣeBadagry Division jẹyọ nínú ìtàn ìbáṣepọ̀ láàrín orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Yúrópù, tí ó sìjẹ́ ibi tí ọjà tí wọn ti ṣòwò ẹrú wà nígbà tí àwọn Bìrìtìkó kó wọn lẹ́rú. Ó tún jẹ́ ibi tí àwọn ẹlẹ́sìn ìgbàgbọ́ ti kọ́kọ́ kéde ìyìn rere ní ọdún 1842 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Èyí di àkọsórí fún Agia Ceotaph.
Àwọn ìjọba ìbílẹ̀
àtúnṣeÀwọn ibùgbé
àtúnṣeAwon ibugbe ni ibile Badagry pin so ona meji. Ikini ni Awori, ikeji si ni ogu tabi egun. Ede ati asa awon meji yato gidi. Amo apere to dara lawon meji nitoripe awon eya mejeji ngbe papo lalafia laisi wahala. Irepo na, lomu pe kosese lati ma pe ilu meji, Iworo to je awori po mo Ajido to je egun, gegebi ikan, Iworo-Ajido.
- Badagry
- Ibereko,kingdom,nigeria
- Oke oko
- Ajara
- Iworo
- Ajido
- Akarakumo
- Gbaji
- Aseri
- Egan
- Aganrin
- Ahanfe
- Epe
- Posi
- Mowo
- Itoga
- Ebiri
- Ekunpa
- Aradagun
- Berekete
- Mosafejo
- Gayingbo-Topo
- Kankon Moba
- Popoji
- Oranyan
- Tafi-Awori
- Yeketome
- Ipota
- Seme Border
- Iyafm
- Farasime
- Mushin
Ibùgbé àwọn àwóri
àtúnṣeÀwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè Àwórì:
- Awodi-Ora
- Ishasi
- Oto-Awori
- Ijanikin
- Ilogbo
- Oko-Afo
- Sibiri
- Apa
- Idoluwo-ile
- Ado-Soba
- Ibeshe
- Irede
- Irese
- Mebamu
- Itewe
- Igede
- Ajangbadi
- lyagbe
- Ajegunie
- Aiyetoro
- Festac Town
- Satellite Town
- Iba
- Kirikiri
- Agboju-Amuwo
- Okokomaiko
- Ojo
- Amukoko
- Alaba-Ore
- Ijoiin
- Igbanko
- Imore
- Ijegun
- Mushin
- Isolo
- Ota
- Itire
- Ipaja
- Agege
- Ibereko
Ibi Àwòrán
àtúnṣe-
First storey building in Nigeria
-
Badagry museum