Baeyer–Drewson indigo synthesis

The Baeyer–Drewson indigo synthesis (1882) jẹ́ ìṣètò ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ organic èyí tí a maa ń ṣètò indigo lati 2-nitrobenzaldehyde àti acetone [1][2]

Baeyer-Drewson indigo synthesis
Baeyer-Drewson indigo synthesis

Wọ́n kó ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ yìí sí aldol condensation. bíi ọnà sí indigo, ìlànà yìí yọ ọ̀nà yìuí kúrò ní aniline.[3]

 
Baeyer-Drewson indigo synthesis mechanism

Àkíyèsí

àtúnṣe

Ní lítíréṣọ̀ Gẹ̀ẹ́sì wọ́n maa ń pe ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́ yìí ní ìdàpọ̀ ṣiṣẹ́ Baeyer–Drewson , bí ó tilẹ̀jẹ́pe ẹní tí ó kọ ìwé àkọ́kọ́ ni Drewsen.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Adolf Baeyer, Viggo Drewsen (1882).
  2. Helmut Schmidt (1997).
  3. Elmar Steingruber "Indigo and Indigo Colorants" Ullmann's Encyclopedia of Industrial Chemistry 2004, Wiley-VCH, Weinheim. doi: 10.1002/14356007.a14_149.pub2