Balogun Market

Oja ni Nigeria

Ọjà Balógun Ajeniya jẹ́ ọjà kan tí ó ṣe pàtàkì tí ó sì wà ní Lagos IslandÌpínlẹ̀ Èkó, Nigeria. Ọjà náà kò ní àdírẹ́ẹ̀sì kan pàtó nítorí pé ó tàn káàkiri ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òpópónà lórí erékùṣù ti Ìpínlẹ̀ náà. Ọjà Balógun jẹ ọjà kan tí ó dára jù nínú gbogbo ọjà tí ó wà ní agbègbè yìí láti ra àwọn aṣọ, bàtà àti gbogbo àwọn nǹkan mèremère tí a lè rà ní ọjà. [1]

Balogun Market, Lagos Island
Ọjà Balógun, Èkó (2007)

Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìjàm̀bá iná

àtúnṣe

Oríṣiríṣi àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí àwọn iná tó ṣé yo ní ọjà olókìkí yìí tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ọjà Balógun, iná náà wáyé ní onírúurú ọjọ́ lóríṣiríṣi ṣùgbọ́n àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàm̀bá iná kan wà tí ó jẹ́ olókìkí wáyé ní Oṣù Kọkànlá ọdún 2019 àti Oṣù Kìíní ọdún 2020, púpọ̀ jùlọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàm̀bá iná máa ń wáyé nínú ọjà yìí ní àsìkò ìgbà ẹ̀rùn.[2]

Wo èyí náà

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Empty citation (help) https://web.archive.org/web/20140316103110/http://deltaskymag.delta.com/Destinations/Lagos/Shopping/Balogun-Market.aspx
  2. http://www.ynaija.com/fire-guts-balogun-market-in-lagos-island-photos/