Bamidele Abiodun
Bamidele Abiodun (tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógún oṣù keje ọdun 1966) jé onisowo, olufuni[1] àti ìyàwó Dapo Abiodun, eniti o jé Gomina ìpínlè Ogun, Nàìjíríà.[2]
Bamidele Abiodun | |
---|---|
H.E, ìyàwó Gomina Ìpínlẹ̀ Ogun, Mrs Bamidele Adiodun | |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Keje 1966 |
Iṣẹ́ | businesswoman, Philanthropist |
Olólùfẹ́ | Dapo Abiodun |
Àárò ayé àti èkó rè
àtúnṣeA bí Abiodun ní July 16, 1966 sí inú idile ojogbon Oladipo Oduye, ígbákejì adari Yunifásitì ìlú ìbàdàn teleri, àti ologbe Abimbola Wosilat Oduye, àwon mejeji jé omo ìlú Ilishan-Remo ní ìpínlè Ogun.[3] Abiodun lo International School ti Ibadan fun èkó Sekondiri rè koto dipe o tèsíwájú ni Yunifásitì ti Ibadan nibi tí o ti gba àmì-èye Bachelor of Science Degree ninú ìmò Zoology ni odun 1988.
Oko òwò àti ìfifúni
àtúnṣeAbiodun bèrè oko owo ni igba 1990s, ó sì ní Ife sí riran obínrin àti omodé lówó, o sì ti ran òpòlopò won lówó nipase ififuni tí oun se.[4], gegebi ìyàwó Gomina ti ìpínlè Ògùn, o ti da opolopo ètò kalè láti ran awon eniyan lowo, àti fún ilosiwaju ètò ara, èkó[5] àti didin ìyà kù. Ní osù kejo odun 2019, Abiodun sisé pèlú Learn Africa plc láti fun awon ilé-ìwé akobere(primary) ati Sekondiri ní egba mejilelogoji(42,000) ní ìwé òfé.[6]
Ìdílé rè
àtúnṣeBamidele Abiodun fé Dapo Abiodun ní odun 1990 wón sì bí omo marun, òkan lara omo won ni ologbe Olugbenga Abiodun, òkan lára awon DJ Nàìjíríà tí òpòlopò mò sí DJ Olu.[7]
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Ogun First Lady, Bamidele Abiodun’s Welfarist Tendencies". THISDAYLIVE. 2019-11-10. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "icons: Bamidele Abiodun (First lady of Ogun State, Nigeria)". Tribune Online. 2021-11-17. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "About Bamidele Abiodun: Nigerian businesswoman and philanthropist (1966-) - Biography, Facts, Career, Life". peoplepill.com. 1966-07-16. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "AJOSE FOUNDATION". AJOSE FOUNDATION. 1966-07-16. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "Bamidele Abiodun - P.M. News". I'm committed to achieving SDG Goal 4. 2019-08-20. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ Akinfenwa, Gbenga (2019-08-04). "Abiodun, Learn Africa donate books, learning materials to Ogun public schools - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2022-05-29. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ Times, Premium (2017-10-14). "Father Of DJ Olu, Mourns Late Son". Sahara Reporters. Retrieved 2022-05-28.