Banky W
Olúbánkọ́lé Wellington (tí a bí ní ọjọ́ ketàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1981),[1] tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Banky W tí ó sì ń jẹ́ Banky Wellington, nínú fíìmù àgbéléwò jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òṣèré àti olóṣèlú.
Banky W | |
---|---|
Banky W. In standing at the left side un black atire. | |
Ọjọ́ìbí | Olubankole Wellington 27 Oṣù Kẹta 1981 New York , United States |
Olólùfẹ́ | Adesua Etomi (m. 2017) |
Musical career | |
Irú orin | R&B |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2002–present |
Labels | Empire Mates Entertainment |
Associated acts | |
Ìgbésí ayé àti ètò-èkó rẹ̀
àtúnṣeUnited States ni a bí Banky W sí, àmọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni àwọn òbí rẹ̀. Nígbà tí ó pé ọmọ ọdún márùn-ún, àwọn òbí rẹ̀ padà sí Nàìjíríà. Láti ìgbà èwe rẹ̀ ni ó ti nífẹ̀ẹ́ sí orin kíkọ, ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ nínú ẹgbẹ́ àwọn akọrin ìjọ rẹ̀. Ìpínlẹ̀ Èkó ní ó ti bẹ̀rẹ̀ ètò-èkó rẹ̀ kí ó tó lọ sí Rensselaer Polytechnic Institute, New York tí ó ti kọ́ ọ parí. Ní ọdún 2002, ó bẹ̀rẹ̀ record label E.M.E. Ó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2009, ó sì dá record label rẹ̀ sílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó. Àwọn tó kó mọ́ra ni Niyola, Shaydee, Skales and Wizkid. Orin rẹ̀, Back in the Building jáde ní ọdún 2005.[2] Òun sì ni ó kọ orin àkọ́kọ́ fún Etisalat Nigeria tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "0809ja for life".[3]
Àkójọpọ̀ orin rẹ̀
àtúnṣe- Studio albums
- Back in the Building (2006)
- Mr. Capable (2008)
- The W Experience (2009)
- R&BW (2013)
- EPs
- Undeniable (2003)
- Playlists
- 2017: Songs About U (2017)
Compilation albums
- Empire Mates State of Mind (2012)
Selected singles
Ààtò Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ tí ó ti gbà
àtúnṣe- John Lennon Song Writing Award 2006, R&B Category, for 'My Regret’
- Best R&B Artiste, Nigerian Entertainment Awards 2006
- Best Male R&B Artiste, Urban Independent Music Awards, USA, 2006
- Best International Album, Nigerian Entertainment Awards 2007 for 'Mr Capable’
- Best R&B Video, Nigerian Music Video Awards 2008 for 'Don't Break My Heart’
- Best Male Vocal Performance, Hip hop World Awards 2009 for 'Don't Break My Heart’
- R&B Single of the year, 2010 Hip Hop World Awards for 'Strong Ting’
- Best R&B Singer (Male) and Best Music Video 2010 City People Entertainment Awards
Àtòjọ Àwọn Eré rẹ̀
àtúnṣe- The Wedding Party (2016)
- The Wedding Party 2 (2017)
- Up North (2018)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The Future Awards 2010: Musician of the Year Nominee Profiles". Ladybrille. 6 January 2010. Archived from the original on 9 June 2010. Retrieved 22 March 2010.
- ↑ Jane Aguoye (9 December 2017). "INTERVIEW: My wife and our new movie — Banky W". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/news/more-news/251972-interview-wife-new-movie-banky-w.html. Retrieved 30 December 2017.
- ↑ "naija 4 life - banky w + Lyrics". Naija Pals. naijapals.com. 11 May 2015. Retrieved 11 May 2018.
- ↑ "High Notes". 360nobs.com. 360nobs. Retrieved 22 June 2016.
- ↑ "High Notes". 360nobs.com. 360nobs. Retrieved 22 June 2016.
- ↑ "High Notes". 360nobs.com. 360nobs. Retrieved 22 June 2016.
- ↑ "All I Want Is You". Pulse.ng. Joey Akan. Archived from the original on 5 December 2015. Retrieved 4 December 2015.
- ↑ "DJ Xclusive Sarkodie, Banky W, Cassper Nyovest, Anatii go hard in 'Cash only' video". Pulse.com.gh. David Mawuli. Retrieved 10 February 2016.
- ↑ "New Music Nikki Laoye – 'Onyeuwaoma' ft Banky W". NotJustok.com. Don Boye. Retrieved 22 April 2016.
- ↑ "New Music Nikki Laoye – 'Onyeuwaoma' ft Banky W". Pulse.ng. Joey Akan. Retrieved 12 February 2016.
- ↑ "Mi Re Do (Cocoloso)". 360nobs.com. 360nobs. Retrieved 22 June 2016.