Barbara Burke
Barbara Burke
Burke (ní apá ọ̀tún) níbi eré ìjọba Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ti ọdún 1938
Ìròyìn ara ẹni
ọjọ́ ìbí ọjọ́ kẹtàlá osù kaàrún ọdún 1917
Norwood, Greater London, UK
ọjọ́ tí ó kú ọjọ́ kẹjọ osù kẹjọ ọdún 1998 (Ọmọ ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rin)Johannesburg, South Africa
Gíga 177 cm (5 ft 10 in)
Ìwòn 63 kg (139 lb)
Eré ìdárayá
Eré ìdárayá Eré sísá
Event(s) Spring, hurdles
Club Mitcham Ladies
Oyè àti Ẹ̀yẹ
Personal best(s) 100 m – 12.2 (1935)
200 m – 24.7 (1935)
80 mH – 11.6 (1937)
Medal record
Sojú Great Britain
Olympic Games
1936 Berlin 4×100 m relay
Sojú South Africa
British Empire Games
1938 Sydney 80 m hurdles
gb
Barbara Hannah Anita Burke tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kaàrún ọdún 1917 tí ó sì kú ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹjọ ọdún 1998 jẹ́ olùsáré jíjá fáfá ọ̀nà tí kò jìn ti Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àti South Africa. Ó kòpa fún Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní summer Olympics ti ọdún 1936, níbití ó ti gba ààmì-ẹ̀yẹ fàdákà kan ní 4 × 100 m tí ó sì se ìkẹẹ̀rin níbi ipari ti eré 100 m.
Níbi àwọn eré ìjọba Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ó kópa nínú ìdíje fun South Africa . Ní ọdún 1934 ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ ti eré ìgba igi fúnra ẹni ti orílẹ̀ ède South Africa èyítí ó parí ṣìkẹrin níbi eré onígi 110-220-110. Nínú ìkọ̀ọ̀kan àwọn eré onígi ti ọgọ́rún àti igba ó lélógún wọ́n yọọ́ kúrò nínú wọn. Ọdún mẹ́rin lẹ́hìnnáà Burke gbégbá orókè níbi ìdíje eré sísá oní fífò ti ọgọ́rin mítà níbi àwọn ọdún 1938. Nínú eré sísá ọgọ́rún àti igba ó lélógún ọ̀pá ó parí ní ìkẹrin sí ìkaàrún.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe
Evans, Hilary; Gjerde, Arild; Heijmans, Jeroen; Mallon, Bill; et al. "Barbara Burke". Olympics at Sports-Reference.com. Sports Reference LLC. Archived from the original on 18 April 2020.
Barbara Burke. trackfield.brinkster.net
<ref>
tag with name "sr" defined in <references>
is not used in prior text.