Barlen Pyamootoo
Barlen Pyamootoo (tí wọ́n bí ní 27 Oṣù Kẹẹ̀sán Ọdún 1960) jẹ́ olùgbéré-jáde olùdarí eré àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Mauritius.[1] Ó gbajúmọ́ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Bénarès.[2]
Barlen Pyamootoo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Barlen Pyamootoo 27 Oṣù Kẹ̀sán 1960 Trou d'Eau Douce, Mauritius |
Orílẹ̀-èdè | Mauritian |
Iṣẹ́ | Director, |
Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Barlen Pyamootoo". The International Writing Program. Retrieved 19 October 2020.
- ↑ "Barlen Pyamootoo: The cosmopolitan island". Beachcomber. Retrieved 19 October 2020.