Bashar al-Assad (Lárúbáwá: بشار حافظ الأسد‎, Baššār al-ʾAsad; ojoibi 11 September 1965) ni Aare orile-ede Orileominira Arabu Siria, Akowe Agbegbe fun Egbe Ba'ath. O di aare ni odun 2000 leyin iku baba re Hafez al-Assad, to joba lori Siria fun odun 29.

Bashar al-Assad
بشار الأسد
President of Syria
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
17 July 2000
Alákóso ÀgbàMuhammad Mustafa Mero
Muhammad Naji al-Otari
Adel Safar
Vice PresidentFarouk al-Sharaa
Najah al-Attar
AsíwájúAbdul Halim Khaddam (Acting)
Leader of the Ba'ath Party
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
10 June 2000
AsíwájúHafez al-Assad
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kẹ̀sán 1965 (1965-09-11) (ọmọ ọdún 59)
Damascus, Syria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúBa'ath Party
(Àwọn) olólùfẹ́Asma al-Akhras
Alma materDamascus University
ProfessionOphthalmologist
WebsiteThe President