Bashir Idris Nadabo
Bashir Idris Nadabo je oloselu ọmọ Nàìjíríà lati ìpínlè Katsina, to soju agbegbe Funtua / Dandume ni ilé ìgbìmò asofin ni ile igbimo aṣòfin agba lati 2003 si 2007. Ó sìn lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Nigeria Peoples Party (ANPP). [1] [2]
Igbesiaye
àtúnṣeBashir Idris Nadabo je oloselu omo Naijiria lati ipinle Katsina ati onisowo ti o ni Al Ihsan Oil and Multi Dynamics Limited. [3]
O ti dibo si ile-igbimọ ijọba apapo ni ọdun 2003 nibiti o ti ṣiṣẹ titi di ọdun 2007. Abdulaziz Ahmed Tijjani ni o tele e. [3] [1]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Empty citation (help) Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name ":0" defined multiple times with different content - ↑ https://citizensciencenigeria.org/public-offices/persons/60157d1e2ab56253bccb475f/
- ↑ 3.0 3.1 Empty citation (help) Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "auto" defined multiple times with different content