Basilea Amoa-Tetteh
Basilea Amoa-Tetteh jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 7, óṣu march ni ọdun 1984. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward[1][2][3]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kẹta 1984 | ||
Playing position | Forward | ||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 20 September 2003 (before the 2003 FIFA Women's World Cup) |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Basilea kopa ninu FIFA Cup awọn obinrin agbaye to waye ni ọdun 2003[4].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-02-03. Retrieved 2022-06-24.
- ↑ https://fbref.com/en/players/ca059820/Basilea-Amoa-Tetteh
- ↑ https://www.worldfootball.net/player_summary/basilea-amoa-tetteh/
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/basilea-amoa-tetteh/291406/