Bauchi Emirate jẹ́ ẹ̀yà Fulani tíwọ́n sedásilẹ̀

Bauchi Emirate jẹ́ ẹ̀yà Fulani tíwọ́n gbẹ́ kalẹ̀ ní bíi igba odún sẹ́yìn ni ìpínlẹ̀ Bauchi loni, nìlẹ̀ Nigeria, tí olú ìlú rẹ̀ jẹ́ Bauchi . Emirate yìí wà lábẹ́ ìdàabọ̀bọ̀ ìlú Gẹ̀ẹ́ṣi ní àkókò ìjoba amúnisìn.

ÌTÀN BAUCHI EMIRATE.

àtúnṣe

Kí Ogun Fulani tó bẹ̀rẹ̀ àwon ẹ̀yà kékèkẹ̀ niwọ́n fi ìlù Bauchi sebùgbẹ̀, lára won èdẹ́ Hausa ni wọ́n nso, tíwọ́n sìjẹ́ elẹ́sìn mùsùlùmí. Ogun Fula èyítí Yàkúbù Gerawa enití ó jẹ́ omo ọ̀kán nínú adarí agbègbẹ́ ìlú saaju rẹ̀ tí ó keko ní ìpínlẹ̀ Sókótó labe Usman Dan Fodio.


ni ó kówon laarin odún 1809 sí 1818.

Èyí lómúkí wọ́n wà lábẹ́ àṣẹ àti ìdarí Fula títí di ọdún 1902. Nígbàtí ìjoba ilẹ̀ Britiko darí olú ìlú Bauchi laisi wàhálà kankan. Àwon niwọ́n fagilé òwò ẹrú tóti gbilẹ̀ kíwọ́n tógbajoba.. Won sì fi Emir tuntun sípò enití o kú lẹ́yìn osù pépéte tó dépò.

Lọ́dún 1904 Emir miiran tó dípò re sẹ́búra nílànà tilẹ̀ Britiko ó ṣì gbadé.

 
Ààfin Bauchi Emirates

Àwọn Emir wọn

àtúnṣe

Àwọn adarí ìÌpínlẹ̀ Bauchi ni wọ́n ma ń jẹ́ Lamido ni

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe