Yunifásítì Báyéró

(Àtúnjúwe láti Bayero University)

Yunifásítì Bayero Kano (BUK) jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ó wà ní Kano, Ìpínlẹ̀ Kano, Nàìjíríà. Ọdún 1975 ni wọ́n da sílẹ̀, nígbà tí wọ́n yí orúkọ rẹ̀ láti Ilé-ìwé gíga Yunifásítì ti Bayero pẹ̀lú ìdàgbàsókè láti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì sí Yunifásítì. Ó jẹ́ Yunifásítì àkọ́kọ́ ní Ìpínlẹ̀ Kano, Àríwá-ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà.

Bayero University Kano
Bayerouniversitylogo.jpg
Motto"وفوق كل ذي علم عليم"
Motto in English"...and above every possessor of knowledge there is one more learned"
Established4 October 1962
TypePublic, research
Vice-ChancellorSagir Adamu Abbas[1]
LocationKano, Kano State, Nigeria
11°58′50″N 8°28′46″E / 11.98056°N 8.47944°E / 11.98056; 8.47944Coordinates: 11°58′50″N 8°28′46″E / 11.98056°N 8.47944°E / 11.98056; 8.47944
CampusUrban
Former namesAhmadu Bello College,
Abdullahi Bayero College,
Bayero University College
Colours     Turquoise
Websitebuk.edu.ng
Yunifásítì Báyéró.



  1. NUC. "List of Universities". Retrieved 5 May 2015.