Beembe
Àwọn beembe ń gbé ni àríwá Zaire ni Congo (Brazzaville) ọ̀nà méjì ni
wọ́n ti wá sí beembe, àwọn kan ti ń gbe ibẹ̀ láti ọdún 1485, nígbà tí
àwọn yapa láti Congo nígbà ogun Portuguese ni Ọdun 1665.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |