Belinda Kanda jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini ọjọ kẹta, óṣu November ni ọ̀dun 1982. Agbabọọlu naa ṣere fun Alabama A&M gẹgẹbi midfielder[1].

Belinda Kanda
Personal information
Ọjọ́ ìbí3 Oṣù Kọkànlá 1982 (1982-11-03) (ọmọ ọdún 42)
Ìga1.68m
Playing positionMidfielder
National team
Ghana women's national football team1(0)
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 10 September 2007 (before the 2007 FIFA Women's World Cup)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Belinda kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2007[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://fbref.com/en/players/2fa0073a/Belinda-Kanda
  2. https://ng.soccerway.com/players/belinda-kanda/19585/