Bella Disu
Belinda "Bella" Ajoke Olubunmi Disu (orúkọ baba rẹ̀ ni Adenuga, wọ́n bí ní 29 May 1986) jé obinrin onísòwò omo Nàìjirià [1]. Òun ni alaga Abumet TNigeria Limited, [2], ígbákejì Alaga ilé ise Globacom, [3], oun sì tún ni oga agba cobble stone property and estate limited ati alaga Julius Berger Nigeria plc [4]
Bella Disu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Belinda Ajoke Olubunmi Adenuga 29 Oṣù Kàrún 1986 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | |
Iṣẹ́ | Business Executive |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Olólùfẹ́ | Jameel Disu |
Parent(s) |
|
Website | bella-disu.com |
Àárò ayé àti èkó rè
àtúnṣeA bí Bella Disu ní 29 may, 1986 sí inú idile Mike Adenuga (alaga Globacom) àti Emelia Adefolake, [5] okawe ní ìlú eko. Ilé ìwé akobere rè ní ilé-ìwé Corona, Victoria Island, ósì lo ilé-ìwé Queen's College fún èkó Sekondiri rè. Ní odun 1998, ófi ilé-ìwé Queen's College kale láti lo si ilé-ìwé Vivian Fowler memorian College for girls, nibi tí o ti pari ìwé sekondiri ní odun 2000 [6].
Ogba àmì-èye Bachelor degree ní sayensi oselu àti International relations ní yunifásitì ti Massachusetts (orílẹ̀ èdè Amerika), ósì tún gba àmì-èye M.sc ninú leadership ní yunifásitì ti Northeastern, Boston [7][8]
Isé rè
àtúnṣeNí odun 2004, Bella darapò mó ilé ise Globacom Ltd, ósì ti di ara àwon oludari ilé isé náà. Ní odun 2011, o di òkan ninú àwon egbe oludari Cobblesrone estate and property Ltd, ósì di ògá àgbà ilé isé náà ní odun 2015. Ó tún jé oludari fún ilé isé Julius Berger tí èka Nàìjíríà. [9] [10] àti oludari Abamet plc, ilé isé tí óún se gilasi àti aluminum ní Nàìjíríà. Ní osù kiní odun 2019, ó di ígbákejì alaga ilé isé Globacom [11]
Ìdílé rè
àtúnṣeNí osù kerin odun 2010, Bella fé Jameel Disu, wón sì bí omo méjì [12]
Àmì èye
àtúnṣeNí December 2019, ìjoba French fún Bella ní àmì èye Ordre des Arts et des Lettres fún ìkópa ré nínú itoju art àti asa papajulo imojuto construction of the Alliance Francaise Mike Adenuga Centre, Ikoyi tí Eko [13]
Àwon ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Women in Business: Bella Disu". Businessday NG. 2019-08-09. Retrieved 2022-03-31.
- ↑ Adeniyi, Olusegun (2021-01-26). "Abumet Nigeria Appoints Belinda Ajoke Disu Chairman". THISDAYLIVE. Retrieved 2022-03-31.
- ↑ "Are you a robot?". Bloomberg. Retrieved 2022-03-31.
- ↑ "Bella DISU". The AFRICA CEO FORUM (in Èdè Faransé). 2021-06-17. Retrieved 2022-03-31.
- ↑ Akinwale, Funsho (2019-03-09). "Bella Adenuga Disu, others bag IoD certification". The Guardian Nigeria News. Archived from the original on 2022-03-31. Retrieved 2022-03-31.
- ↑ Olanrewaju, Sulaimon (2019-04-12). "Bella Disu: The Midas at Globacom". Tribune Online. Retrieved 2022-04-01.
- ↑ Uriri, Francesca (2019-03-16). "Leading Ladies Africa Nigeria’s 100 most inspiring women in 2019". Guardian Woman. Retrieved 2022-04-01.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ THISDAYLIVE, Home - (2018-10-07). "– A Daughter in a Million: The Amazing Exploits of Belinda Disu in BusinesTHISDAYLIVE". THISDAYLIVE. Retrieved 2022-04-01.
- ↑ Ojekunle, Aderemi (2018-07-20). "Meet the daughters of 6 Nigerian billionaires and what they do". Business Insider Africa. Retrieved 2022-04-01.
- ↑ "Globacom’s EVC, Bella Disu, Joins Others for Institute of Directors Certification". Nigerian CommunicationWeek. 2019-03-05. Retrieved 2022-04-01.
- ↑ "Adenuga’s Daughter Assumes Number 2 Role At Globacom". Technology Times. 2019-01-30. Retrieved 2022-04-01.
- ↑ "Classics: Inside Bella Adenuga, Jameel Disu's Engagement". Encomium Magazine. 2010-04-10. Retrieved 2022-04-01.
- ↑ Omotayo, Joseph (2019-12-18). "Jubilation as Mike Adenuga’s daughter bags French prestigious national honour". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2022-04-01.