Beloved Isle Cayman
Beloved Isle Cayman ni orin orile-ede onibise Àwọn Erékùṣù Káímàn ti Leila Ross-Shier ko ni 1930. Bi Ileagbegbe Okere Britani, orin-iyin orile-ede onibise ni God Save the Queen.
Orin-ìyìn ileagbegbe | Cayman Islands |
---|---|
Ọ̀rọ̀ orin | Leila Ross-Shier |
Orin | Leila Ross-Shier |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |