Ben Chijoke (TY)
Ben Chijioke tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ty ni Wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1972, tí ó sìn ṣaláìsí lọ́jọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 2020 (17 August 1972 – 7 May 2020), jẹ́ olórin tàkasúfèé lórílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà]].[1] Ó ṣe àwo orin tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Awkward lodun 2001, bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe àwo orin mìíràn tí ó pè ní Upwards lọ́dún 2004, Closer lọ́dún 2006, Special Kind of Fool lọ́dún 2010 àti A Work of Heart lọ́dún 2018. Wọ́n yàn àwo orin Upwards fún Àmìn-ẹ̀yẹ Mercury Prize.[2] Ty tí bá àwọn gbajúmọ̀ olórin bii Shortee Blitz,[3] Drew Horley,[4] àti Tony Allen.[5] ṣe àjọṣe pọ̀ àwo.
Ty | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Benedict Chijioke |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | T.Y. |
Ọjọ́ìbí | London, England, UK | 17 Oṣù Kẹjọ 1972
Ìbẹ̀rẹ̀ | Brixton, South London, UK |
Aláìsí | 7 May 2020 London, England, UK | (ọmọ ọdún 47)
Irú orin | Hip hop |
Occupation(s) | Vocalist, rapper, producer |
Instruments | Vocals |
Years active | 1990s–2020 |
Labels | BBE, Big Dada, Jazz re:freshed |
Associated acts | Shortee Blitz, Drew Horley, Tony Allen |
Website | tymusic.co.uk |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Savage, Mark (7 May 2020). "UK rapper Ty dies of coronavirus, aged 47". BBC News. https://www.bbc.com/news/entertainment-arts-52584834. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ Reporters, Telegraph (8 May 2020). "Ty dies aged 47: Tributes flow for British rapper who contracted coronavirus". The Telegraph. ISSN 0307-1235. https://www.telegraph.co.uk/news/2020/05/08/ty-dies-aged-47-tributes-flow-british-rapper-contracted-coronavirus/. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ Johns, Darren (28 February 2001). "TY: Awkward". NME.
- ↑ Longley, Martin (2010). "Ty – Special Kind of Fool – Review". BBC.
- ↑ Cowie, Del F. (March 2004). "Ty – Upwards". Exclaim!.