Berhane Adere Debala ni a bini ọjọ kọkan leelogun, óṣu July, ọdun 1973 jẹ elere sisa lobinrin to ti fẹyinti ti órilẹ ede Ethiopia to da lori metres ti ẹgbẹrun mẹwa ati Marathon[1].

Berhane Adere
Berhane Adere
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Berhane Adere Debala
Ọjọ́ìbí21 Oṣù Keje 1973 (1973-07-21) (ọmọ ọdún 51)
Shewa, Ethiopia
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáTrack and field
Event(s)Long-distance running

Àṣèyọri

àtúnṣe

Ni ọdun 2001 ati 2005, Berhane gba ami ẹyẹ ti ọla ti Silver ninu idije agbaye. Ni ọdun 2002, Arabinrin naa jẹ champion ti agbaye to si tun gba silver ni ọdun 2003 ati idẹ ni 2001. Ni ọdun 2003, Berhane gba ami ẹyẹ ti ọla ti Wura ninu idije agbaye ninu metres ti ẹgbẹrun marun. Berhane gba akọsilẹ fun ilẹ Africa lori metres ẹgbẹrun ati wakati 30:04 ni idije agbaye to waye ni 2003 to si gba wura. Ni ọdun 2003 ati 2004, Berhane gba wura ati silver ninu idije agbaye ti inule lori metres ti ẹgbẹrun mẹta[2]. Berhane yege ninu Marathon ti ilẹ Chicago ni ọdun 2006 pẹlu wakati 2:20:42 ati 2007[3][4]. Ni ọdun 2007, Arabinrin naa yege lori Marathon ti Idaji Ras Al Khaimah. Ni ọjọ keji leelogun, óṣu January, ọdun 2008, Berhane yege ninu Marathon ti ilẹ Dubai[5].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. Berhane ADERE Profile
  2. 3000m final at the World Athletics Indoor Championships
  3. Two Time Chicago Marathon Champion
  4. Chicago Marathon
  5. Dubai Marathon