Betty Aberlin

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Betty Aberlin (ti a bi Betty Kay Ageloff Oṣu kejila ọjọ 30, ọdun 1942, Ilu New York ) jẹ oṣere Amẹrika kan, akewi, ati onkọwe . O ni ipa deede lori eto Awọn arakunrin Smothers (Smothers Brothers Show) . Aberlin ṣiṣẹ lori ọpọlọpọ awọn eto tẹlifisiọnu . O ṣere Arabinrin Aberlin ninu eree Adugbo Ogbeni Rogers (Mister Rogers' Neighborhood) . Awọn ipa fiimu rẹ pẹlu iṣẹ ni Dogma ati Jersey Girl .

Betty Aberlin
Ọjọ́ìbíBetty Kay Ageloff
30 Oṣù Kejìlá 1942 (1942-12-30) (ọmọ ọdún 82)
New York, New York, USA


Awọn itọkas[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

àtúnṣe
  1. ↑ "Betty Aberlin Bio Biography". TV Rage. Archived from the original on January 17, 2012. Retrieved January 1, 2013.

Awọn oju opo wẹẹbu miiran

àtúnṣe
  • Betty Aberlin on IMDb

Àdàkọ:Mister Rogers' Neighborhood