Beverly Osu
Beverly Ada Mary Osu tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀ oṣù Kẹjọ ọdún 1992 (September 27,1992) jẹ́ alájótà oníhòhò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] ó di ìlú mọ̀ọ́ká lórí àwọn ipa rẹ̀ ní oríṣiríṣi sinimá àti ipa tí oko ní inú Big Brother Africa ẹlẹ́kẹjọ Irú rẹ̀.[2][3] Ó gba àmì-ẹyẹ ti Dynamix All Youth Awards ti ọdún 2011.[4]
Beverly Osu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Beverly Ada Mary Osu 27 Oṣù Kẹ̀sán 1992 Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Babcock University and National Open University of Nigeria |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2011-Present |
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeOsu, jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Delta àmọ́ tí wọ́n bí sí Ìpínlẹ̀ Èkó.[5] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Daughters of Divine Love Convent, tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Enugu, nígbà tí ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Babcock, láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Ibà ọ̀pọ̀ ènìyàn sọ̀rọ̀ (mass communication), àmọ́ kò parí níbẹ̀. Ẹ̀wẹ̀, ó darí ẹ̀kọ́ rẹ̀ sí National Open University of Nigeria láti parí ìkẹ́kọ́ gboyè rẹ̀ láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Babcock. [6] .[2][7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Rapheal (2019-10-12). "99 percent of women fake orgasm – Beverly Osu". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-14.
- ↑ 2.0 2.1 Chinasa, Hannah (2017-02-23). "Beverly Osu: Life and modelling career". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-14. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ RITA (2019-06-26). "Cosmetic surgery: Beverly Osu issues advice to ladies". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-14.
- ↑ "Beverly Osu defends racy pictures in nun outfit, says 'I'm Catholic'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-11. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Beverly Osu – 10 Things You Didn’t Know About This Actress/Model". BuzzNigeria - Famous People, Celebrity Bios, Updates and Trendy News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-07. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ "The Many Lies Of Beverly Osu". www.pulse.ng. Archived from the original on 2019-12-14. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ Published. "I received death threats over racy nun pictures I took –Beverly Osu". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-14.