Bifid penis
Bifid penis (tàbí okó méjì) jẹ́ àrùn abínibí tí kò wọ́pọ̀ léyí tí genital tubercle méjì maa ń yọ jáde.[1][2]
Ìtàn sọọ́ di mímọ̀ wípé àwọn ọmọkùnrin tí wọ́n bí pẹ̀lú okó méjì maa ṣisẹ́ abẹ lati to okó wọ́n dáradára. Wọ́n tọ́ wọn bí obìrin tí wọ́n sì ṣiṣẹ́ abẹ fún wọn kí wọ́n lè dàbí obìnrin tí wọ́n a sí fi iṣẹ́ abẹ fí àwọn ohun tí ó ń jẹ́ kí ènìyàn jẹ́ obìnrin sí wọn lára. Ní òde òní, wọ́n kò tẹ́lé ìlànà yìí mọ́, tí wọ́n sì ń ṣàyẹ̀wò fínífíní lórí rẹ̀ nítorí àìrọ́mọbí àwọn ọmọ tí wọ́n bá sọ dobìrin.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Lewis, Keeta D. & Bear, Bonnie (2002). Manual of school health. Elsevier Health Sciences. p. 161. ISBN 978-0-7216-8521-2. http://books.google.com/books?id=oxVbpsrlvPsC&pg=PA161.
- ↑ Jones, Richard E. & López, Kristin H. (2006). Human reproductive biology (3rd ed.). Academic Press. p. 145. ISBN 978-0-12-088465-0. http://books.google.com/books?id=pfiZfui2XLIC&pg=PA145.
- ↑ Puri, Prem & Höllwarth, Michael (2009). Pediatric Surgery: Diagnosis and Management. Springer. pp. 639–640. ISBN 978-3-540-69559-2. http://books.google.com/books?id=8A70xzrxK9EC&pg=PA639.