Bilal Ibn Rabah
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the companion of Muhammad. Fún the Mosque named in his honour, ẹ wo: Rachel's tomb.
Bilāl ibn Rabāḥ (Lárúbáwá: بِلَال بِن رَبَاح), c. 580–640, jẹ́ ọ̀kan lára sàhabé tí Ànọ́bì Muhammad (S.W.T) gbẹ́kẹ̀le tí ó sí fọkàntàn tí Ànọ́bi náà sì jẹ́ ọ̀kan lára òjíṣẹ́ tí Ọlọ́run ran sí àwọn mùsùlùmí. Wọ́n bi sí Ìlu Mecca, tí wọ́n ṣì gbà ọ òun nì Mu'azzin àkọ́kọ́ nínú ìtàn, tíó jẹ́ pé ànọ́bí gan-an fúnrarẹ̀ ni ó yàn.[1][4][5][6] Ó jẹ́ ẹrú kan tẹ́lẹ̀rí tí ó wá láti Orílé èdè Ethiopia, tí ó sì jẹ́ olókìkí látàrí òhun dídùn tí ó ní tí ó sì fí ń pè àwọn ẹrùsìn ọlọ́run láti wà kí Ìrun. Ó jáde láyé ní Odún 640, tí ó sì wà ní ọmọ ọgọ́ta ọdún.
Bilāl ibn Rabāḥ بِلَال بِن رَبَاح | |
---|---|
Born | 580 CE |
Birthplace | Mecca, Hejaz |
Known for | being the first mu'azzin in Islam history [1][2] |
Occupation | Muezzin and Secretary of Treasure of The Islamic State of Medina |
Title | Sayyid al-Muʾaḏḏin |
Died | March 2, 640 | (ọmọ ọdún 59–60) CE
Father | Rabah |
Mother | Hamamah |
Wife |
|
Religion | Islam |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Slavery in Islam." BBC News. BBC, 2009. Web. 2013.
- ↑ Riz̤vī, Sayyid Sa'eed Ak̲h̲tar. Slavery: From Islamic & Christian Perspectives. Richmond, British Columbia: Vancouver Islamic Educational Foundation, 1988. Print. ISBN 0-920675-07-7 Pg. 35-36
- ↑ "الإصابة في تمييز الصحابة، لابن حجر العسقلاني، ترجمة هالة بنت عوف الزهرية، موقع صحابة رسولنا". Archived from the original on 2018-07-15. Retrieved 2021-05-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Ludwig W. Adamec (2009), Historical Dictionary of Islam, p.68. Scarecrow Press. ISBN 0810861615.
- ↑ Robinson, David. Muslim Societies in African History. Cambridge, UK: Cambridge University Press, 2004. Print.
- ↑ Levtzion, Nehemia, and Randall Lee Pouwels. The History of Islam in Africa. South Africa: Ohio UP, 2000. Print.