Bilikiss Adebiyi Abiola
Bilikiss Adebiyi tabi Bilikiss Adebiyi Abiola jẹ́
Bilikiss Adebiyi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Eko, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Bilikiss Adebiyi Abiola |
Gbajúmọ̀ fún | CEO of Wecyclers |
́ ọmọ Nàìjíríà, Aláṣẹ Iléeìsọstí-dọ̀tun Wecyclers ní Ìlú Èkó (Lagos - based recycling company Wecyclers). Ó gbàgbọ̀ pé ẹ̀kọ́ ẹlẹ́kọ́ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà. Tòun ti iléeṣẹ́ rẹ̀ ti gba àmì-ẹ̀yẹ púpọ̀ lára wọn ni ẹ̀bùn King Baudouin International Development Prize ní 2018/19
Ibẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé
àtúnṣeÌlú Èkó ni wọ́n bí Adébìyí sí, níbi tí ó lọ sí lle ẹ̀kọ́ Gíga Supreme Education Foundation. Ó lọ sí Yunifásítì Ìjọba Àpapọ̀ tí ìlú Èkó, ṣùgbọ́n ó kúrò lẹ́yìn ọdún kan tí ó wọlé láti lọ sí ìlú Amẹ́ríkà lọ parí ẹ̀kọ́ rẹ̀. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ni Yunifásítì Fisk ó sì tẹ̀síwájú sí Yunifásítì Vanderbilt níbi tí ó lọ gba oyè Master's. Ó ṣiṣẹ́ ní IBM fún ọdún márùn-ún kí ó tó pinnu láti kẹ́kọ̀ọ́ sí i. Wọ́n gbà á sí Massachusetts Institute of Technology (MIT) láti wá kẹ́kọ̀ọ́ Master nínú Imọ̀ Ìṣàkóso ìṣòwò (Business Administration
Wecyclers
àtúnṣeÈrò ìṣòwò ìsọdọ̀tun sọ si lọ́kàn nígbà tí ó wà ní ipele kejì ní MIT, níbi tí ó ti ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìdọ̀tí gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ àfojúsùn rẹ̀. Èròngba rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ni láti mú àlékún bá iye ìdọ̀tí tí ó n gba lọ́wọ́ ilé kí ó sì fún wọ́n ni ìwé pélébé ìgbẹ́bùn(raffle ticket). Nígbà tí ó wà sí Nàìjíríà fún ìsinmi, ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fún pé nígbà tí ó ṣòrọ̀ lórí èrò rẹ̀, tọwọ́tẹsẹ̀ ni wọ́n fi gbà á. Ohun ìtìjú ni ìdọ̀tí jẹ́ ní Èkó torí pé ìdá ìdọ̀tí kékeré ni wọ́n ń gbà. Adebiyi fi èrò rẹ̀ lọ MIT níbi tí ó ti rí àtìlẹhìn nípa Ìdíje ṣíṣe. Lẹ́yìn ti ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè tan ni ọdún 2012, ó padà sí Nàìjíríà láti wà pẹ̀lú ọkọ rẹ.
Wo eléyìí náà
àtúnṣe- <a href="./https://en.wikipedia.org/wiki/Dupsy_Abiola" rel="mw:WikiLink" data-linkid="89" class="cx-link" title="Dupsy Abiola">Dupsy Abiola</a>
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adebiyi-Abiola: Iboju Isinmi Titun Ni Nigeria , NGRGuardian, Ti gba pada ni 28 Kínní 2016
- ↑ Egbin ni, Owo Jade: Ika mi pẹlu Bilikiss Adebiyi-Abiola , 2014, Ile-iwe Huffington , Ti gba pada ni 28 Kínní 2016