Bilkisu Yusuf, tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí Hajiya Bilkisu Yusuf, (ọjọ́ kejì oṣù Kejìlá ọdun 1952 – ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹsàn 2015), jé oníròyìn àti akọròyìn fún àwọn ilé ìròyìn tó gbajúmọ̀ ní Abuja, Ìlú Kano àti Kaduna, ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Hajiya
Bilkisu Yusuf
Fáìlì:Bilkisu-Yusef.jpg
Ọjọ́ìbí2 December 1952
Aláìsí24 September 2015(2015-09-24) (ọmọ ọdún 62)
Mina, Saudi Arabia
Cause of deathCrowd crush
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Ahmadu Bello University (Bachelors);
University of Wisconsin-Madison (Masters);
Moscow State Institute of Journalism and International Relations
Iléẹ̀kọ́ gígaAnsar Primary School, Kano (1964)
Government Girls College, Dala, Kano
Iṣẹ́Journalist, columnist and editor
EmployerDaily Trust and Leadership newspapers
OrganizationWomen In Nigeria;
Federation of Muslim Women's Associations in Nigeria,
Advocacy Nigeria
Gbajúmọ̀ fúnJournalism and women's rights activist
Olólùfẹ́Alhaji Sanusi Ciroma Yusuf (first husband)
Mustapha Bintube (second husband)
Àwọn ọmọMoshood Sanusi Yusuf (son) & Nana Fatima (daughter)

Bilkisu jẹ́ ẹ̀yà ọmọ Yorùbá máa mọ́ Hausa, Mùsùlùmí, àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn obìnrin, òun ni ó ń gba ààrẹ ní ìmọ̀ràn lórí àwọn ọ̀rọ̀ tó bá pa Nàìjíríà papọ̀ mọ́ òkè òkun àti nípa dídá àwọn ààjọ tí kò sí lábé ìdarí ìjọba kalẹ̀, àwọn ààjọ bi Women In Nigeria (WIN) àti the Federation of Muslim Women's Association (FOMWAN). Yusuf fi ayé sílè látàrí ìtẹ̀pa 2015 Mina stampede nígbà tí ó wà ní HajMecca, Saudi Arabia.[1][2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Lost in the Hajj stampede was a pioneering journalist who united Christians and Muslims". Public Radio International. September 29, 2015. 
  2. Chesa, Chesa; Oyoyo, Juliet; Faturoti, Gbenga. "Female Editor, Bilikisu; El-Miskeen, 4 Others Die In Hajj Stampede". Dailyindependentnig.com. Archived from the original on 2015-09-30. Retrieved 2015-10-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)