Bill Gates
William Henry "Bill" Gates III tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1955 (28th/10/1955)[2] jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Amerika, alaanu, oludako ati alaga[3] ilé-iṣẹ́ Microsoft, ilé-iṣẹ́ atolànà kọ̀m̀pútà tó dá sílẹ̀ pẹ̀lú Paul Allen. Gates jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó lọ́wọ́ jùlọ lágbàáyé[4] òun sì ni olówó jùlọ ní àgbáyé lọ́dún 1995, 2009, àyàfi ọdún 2008, nígbà tó bọ́ sí ipò kẹta.[5] Nígbà tó fi ṣíṣe ní Microsoft, Gates wà ní ipò CEO àti amójútó àgbà atolànà kọ̀m̀pútà, bẹ́ẹ̀ sì ni òun ni onípìn-ín ìdákowò tó tóbi jù lọ, ipin ajoni.[6] Ó tún ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé.
Bill Gates | |
---|---|
Bill Gates at the World Economic Forum in Davos, 2007 | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀wá 1955 Seattle, Washington, USA |
Ibùgbé | Medina, WA |
Orílẹ̀-èdè | American |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Harvard University (dropped out in 1975) |
Iṣẹ́ | Chairman of Microsoft (non-executive) Co-Chair of Bill & Melinda Gates Foundation Director of Berkshire Hathaway CEO of Cascade Investment |
Net worth | Àdàkọ:GainUS$54 billion (2010)[1] |
Olólùfẹ́ | Melinda Gates (m. 1994) |
Àwọn ọmọ | 3 |
Parent(s) | William H. Gates, Sr. Mary Maxwell Gates |
Website | Bill Gates |
Signature | |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Bill Gates topic page. Forbes.com. Retrieved September 2010.
- ↑ Àdàkọ:Harv
- ↑ Chapman, Glenn (June 27, 2008). "Bill Gates Signs Off". Agence France-Presse. Archived from the original on June 30, 2008. https://web.archive.org/web/20080630070506/http://afp.google.com/article/ALeqM5i8aV1bK5vmwLaw9wYr9nY5bFc4YA.
- ↑ Wahba, Phil (September 17, 2008). "Bill Gates tops U.S. wealth list 15 years in a row". Reuters. http://www.reuters.com/article/rbssTechMediaTelecomNews/idUSN1748882920080917. Retrieved November 6, 2008.
- ↑ [1] Forbes.com. Retrieved April 2010.
- ↑ Gates regularly documents his share ownership through public SEC form 4 filings.