Billie Eilish
Billie Eilish Pirate Baird O'Connell ( /ˈaɪlɪʃ/ EYE-lish;[2] tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kejìlá ọdún 2001) jẹ́ akọrin ọmọ orílè-èdè Amerika. Ó di gbajúgbajà ní ọdún 2015 nígbà tí ó ṣe àgbéjáde orin "Ocean Eyes", tí arákùnrin rẹ̀ Finneas O'Connell kọ sílẹ̀. Ní ọdún 2017, ó sàgbéjáde orin extended play (EP), Don't Smile at Me.
Billie Eilish | ||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Eilish ní ọdún 2023 | ||||||||
Ọjọ́ìbí | Billie Eilish Pirate Baird O'Connell 18 Oṣù Kejìlá 2001 Los Angeles, California, U.S. | |||||||
Iṣẹ́ |
| |||||||
Ìgbà iṣẹ́ | 2015–present | |||||||
Works | ||||||||
Parent(s) |
| |||||||
Àwọn olùbátan | Finneas O'Connell (brother) Brian Baird (uncle) | |||||||
Awards | Full list | |||||||
Musical career | ||||||||
Irú orin | ||||||||
Instruments |
| |||||||
Labels |
| |||||||
Website | billieeilish.com | |||||||
| ||||||||
Signature | ||||||||
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Pop Rock Music Guide: A Brief History of Pop Rock - 2023 - MasterClass". February 8, 2022. Archived from the original on October 2, 2023. Retrieved February 6, 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Savage, Mark (July 15, 2017). "Billie Eilish: Is she pop's best new hope?". BBC News. https://www.bbc.com/news/entertainment-arts-40580489. ""...It's eye-lish, like eyelash with a lish.""