Billy Crudup
William Gaither Crudup ( /ˈkruːdəp/; tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1968)[1] jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè Amẹ́ríkà. Ipá rẹ̀ nínú fíìmù Jesus' Son (1999) jẹ́ kí wón yàn mọ́ àwọn tí ó tó sí Independent Spirit Award for Best Male Lead. Ó tún ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré bi Almost Famous (2000), Big Fish (2003), Mission: Impossible III (2006), Watchmen (2009), Public Enemies (2009), The Stanford Prison Experiment (2015), Jackie (2016), àti Alien: Covenant (2017).
Billy Crudup | |
---|---|
Crudup ní ọdún 2015 | |
Ọjọ́ìbí | William Gaither Crudup 8 Oṣù Keje 1968 Manhasset, New York, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | University of North Carolina, Chapel Hill (BA) New York University (MFA) |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1989–present |
Olólùfẹ́ | Naomi Watts (m. 2023) |
Alábàálòpọ̀ | Mary-Louise Parker (1996–2004) Claire Danes (2004–2006) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Crudup gba àmì-ẹ̀yẹ Tony Award fún ipa rẹ̀ nínú fíìmù Tom Stoppard tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Coast of Utopia (2007). Ó tún ti ṣeré nínú àwọn eré bi Gypsy (2017), The Morning Show (2019), èyí tí ó mú kí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Primetime Emmy Award àti Critics' Choice Television Award.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Birthdays". The Modesto Bee. Associated Press: p. 2A. July 8, 2022. "Actor Billy Crudup is 54."