Bimbo Ademoye
Bímbọ́ Adémóyè jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2018 ni wọ́n yàn án fún amì-ẹ̀yẹ òṣèré tí ó dára jùlọ nínú eré ìpanilẹ́rìn-ín / TV Jara ní ọ̀wọ́ Àṣàyàn Áfíríkà fún ipa rè nínu fíìmù Backup Wife (2017). Ó tún ńṣe ìràwọ̀ ROK TV, ìkànnì 329.[1]
Bimbo Ademoye | |
---|---|
Bimbo Ademoye nínú Sugar Rush | |
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ Kẹrin, Oṣù Kẹrin , ọdún 1991 Lagos |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Ile-iwe Covenant |
Iṣẹ́ | òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2014- till date |
Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé àti ẹkọ rẹ̀
àtúnṣeA bí Adémóyè ní ọjọ́ kẹrin, oṣù kẹrin , ọdún 1991, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, gúúsù ìwọ̀ òrùn Nàìjíríà . Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ àgbà Yunifásitì Covenant níbi tí ó tí kẹ́kọ̀ọ́ Ìṣàkóso ìṣòwò . Nínu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú ìwé ìròyìn The Punch ó sọ pé bàbá òun nìkan ni ó ṣe àtìleyín fún iṣẹ́ tí òun yàn láàyò[2] .[3][4]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeNínu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú ìwé ìròyìn Daily Independent, ó sọ pé iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2014 nígbàtí wọ́n gbe sínu fíìmù kúkúrú Where Talent Lies fíìmù náà gba àwọn ìyìn láti Ayẹyẹ Fíìmù Káríayé Áfíríkà [5]. Ó ṣe àpèjúwe Uduak Isong gẹ́gẹ́ bi olùkọ́ rẹ̀, ẹni tí ó ṣe ìrànlọ́wọ́ fun láti wọ ibi iṣẹ́ náà . Ní ọdún 2015, a gbé jáde ní fíìmù ẹ̀yà àkọ́kọ́ It's about your husband èyítí ó tún ṣe nípasẹ̀ Isong. Nínú àkójọ pọ̀ 2018 nípasẹ̀ ìwé ìròyìn Premium Times, Ademoye jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn òṣèré márùn-ún tí o ní àsọtẹ́lẹ̀ láti ní iṣẹ́ àṣeyọrí ṣáájú òpin ọdún .
Ní Oṣù Kẹrin ọdún 2018, ó ṣe alábáṣìsẹ́pọ̀ pẹlu Stella Damasus nínú Gone, tí Daniel Ademinokan ṣe olùdarí . Ó ṣe àpèjúwe ṣiṣẹ́ iṣé pẹ̀lú Damasus gẹ́gẹ́bí àkókò ìwúrí fún iṣẹ́ rẹ̀ . Ní 2018 City People Movie Awards ,ó yàn fún Ìfihàn ti Ọdún, Òṣèré Tuntun Tuntun tó dára jù lọ àti Òṣèré àṣẹ̀ṣẹ̀bẹ̀rẹ̀ tó dára jùlọ. Ipa rẹ̀ nínu Backup Wife tún jẹ́ kí ó gba yíyàn fún Best Lead Role ní 2018' Nigeria Entertainment Awards. Ó gbà àwọn ẹ̀bùn méjì ní 2018 Best of Nollywood Awards fún ipa rè nínu' Personal Assistant, ó sì gba ẹ̀bùn fún Òṣèré tí ó dára jùlọ nínú ipa àtìlẹ́yìn óssì gba yíyàn fún Best Kiss in a movie.
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe- Awọn ọrẹbinrin (2019)
- Idile (2019)
- Kamsi (2018)
- Gbigba Rẹ (2018)
- Imọlẹ ninu Okunkun (2018)
- Oluranlọwọ Ti ara ẹni (2018)
- Awọn ọmọ ilebinrin ti o nireti
- Ti pari (2018)
- Awọn Ọjọ Tẹhin
- Iyawo Afẹyinti
- Iwe ito iṣẹlẹ ojojumọ ti Obirin ara Ilu Nigeria
- O jẹ Nipa Ọkọ Rẹ
- Charmed
- Rofia Tai Loran
- Eleyi jẹ O (2016)
- Nwa fun Baami (2019)
- Lero Bi Ọrun (2019)
- Arọwọto (2019)
- Apo pataki (2019)
- Olufẹ Affy (2020)
- Arọwọto (2020)
Awọn àmì ẹ̀yẹ
àtúnṣeYear | Event | Category | Result | Ref |
---|---|---|---|---|
2017 | Best of Nollywood Awards | Revelation of the Year –female | Wọ́n pèé | [6] |
2018 | Best of Nollywood Awards | Best supporting actress | Gbàá | [7] |
Best Kiss in a Movie | Wọ́n pèé | [8] | ||
2019 | City People Movie Award | Most Featured Actress In Cinema Movies | Gbàá | |
2020 | AMVCA | Actress in a Comedy (Movie/TV Series) | Wọ́n pèé | [9] |
Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Supporting Role (English) | Gbàá | [10] | |
2022 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress in A Comedy | Wọ́n pèé | |
2023 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress In A Comedy/TV Series | Gbàá | [11][12] |
Best Actress In A Drama, Movie Or TV Series | Wọ́n pèé | |||
Best Online Social Content Creator | Wọ́n pèé |
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.thisdaylive.com/index.php/2019/02/09/bimbo-ademoye-marks-birthday-in-style/
- ↑ https://punchng.com/my-dad-took-me-to-my-first-audition-bimbo-ademoye/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-10-13. Retrieved 2020-10-11.
- ↑ http://www.ghafla.com/ng/actress-bimbo-ademoye-celebrates-her-birthday-with-stunning-photos/
- ↑ https://www.independent.ng/dont-enjoy-single/
- ↑ "BON Awards 2017: Kannywood’s Ali Nuhu receives Special Recognition Award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-11-23. Retrieved 2021-10-07.
- ↑ "BON Awards 2018: Tope Oshin, Tana Adelana win big" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-10. Retrieved 2020-10-05.
- ↑ "BON Awards 2018: Mercy Aigbe, Tana Adelana shine at 10th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-09. Retrieved 2019-12-23.
- ↑ "Nigerian actress Bimbo Ademoye celebrates AMVCA nomination". Sidomex Entertainment (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-09. Retrieved 2020-10-05.
- ↑ Augoye, Jayne (2020-12-07). "BON Awards: Laura Fidel, Kunle Remi win Best Kiss (Full List of Winners)" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees". AMVCA - Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-23.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "AMVCA 2023: Bimbo Ademoye wins Best Actress in Comedy". Vanguard News. 2023-05-20. Retrieved 2023-06-01.