Bioclinix Medical Diagnostics Centre

Bioclinix Medical Diagnostics Centre jẹ́ Ilé-àyẹ̀wò-ara aládàáni tí ó ní àṣẹ àti oǹtẹ̀ ìjọba Ìpínlè Èkó láti ọwọ́ àjọ tí ó ń m'ójú tó nǹkan ètò-ìlera, Health Facility Monitoring and Accreditation Agency (HEFAMAA) [1][2] láti máa ṣe àyẹ̀wò ara fún oríṣiríṣi àìsàn àti àìlera lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan.[3]. Ilé-àyẹ̀wò-ara aládàáni yìí wà ní ìlú Badagry, Ìpínlẹ̀ Èkó, l'órílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Bioclinix Diagnostics Care Limited, Mowo, Badagry, Lagos State

Ọ̀pọ̀ ìgbà ní ilé-iṣẹ́ náà máa ń ṣe àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ àti ẹ̀dínwó fún àwọn olùgbé Badagry àti àgbègbè, rẹ̀ kí wọ́n ba lè ní aǹfàní láti ṣe ìtọ́jú tó péye fún àgọ́-ara wọn[4].

Àwọn ẹ̀ka àyẹ̀wò-ara

àtúnṣe

Ilé-àyẹ̀wò-ara yìí ní ẹ̀ka àyẹ̀wò-ara lóríṣiríṣị tí wọ́n ń ṣe fún àwọn ará ìlú. Lára wọn ni:

  • Haematology
  • Biochemistry
  • Pathology
  • Serology
  • Cytology
  • Microbiology
  • Endocrinology
  • Cardiology
  • Radiology

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Bioclinix Bolsters Diagnosis Service, Becomes HEFAMAA Certified – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. 2024-07-19. Retrieved 2024-09-19. 
  2. Nigeria, Guardian (2024-07-14). "HEFAMAA certifies Bioclinix: A new era for medical diagnostics in Badagry". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2024-09-19. 
  3. "Bioclinix". Bioclinix. 2024-06-17. Retrieved 2024-09-09. 
  4. Nigeria, Guardian (2024-08-13). "Bioclinix Medical Diagnostics Centre to subsidize diagnostic services for senior citizens in Badagry". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2024-09-09.