Birhane Dibaba
Birhane Dibaba tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá, oṣù kẹsàn-án, ọdún 1993 jẹ́ ọmọbìnrin eléré sísá ti ọ̀nà jínjìn tó dá lórí ìdíje ti eré sísá ti ojú ọ̀nà[1][2][3].
Òrọ̀ ẹni | ||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹ̀sán 1993 | |||||||||
Height | 1.60 m (5 ft 3 in) | |||||||||
Weight | 4kg | |||||||||
Sport | ||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | |||||||||
Erẹ́ìdárayá | Athletics | |||||||||
Event(s) | Marathon | |||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣeyọrí
àtúnṣeNí ọdún 2014, Dibaba kópa nínú Marathon ti Tokyo tó sì gbé ipò kejì láàárín wákàtí 2:22:30. Ní ọdún 2015, Birhane kópa nínú Marathon ti Tokyo tó sì gbé ipò àkọ́kọ́ láàárín wákàtí 2:23:15[4]. Ní ọdún 2015, Birhane ni a yàn gẹ́gẹ́ bíi ọ̀kan lára àwọn obìnrin tó yege nínú eré sísá ní ìdíje àgbáyé láti ṣojú fún ẹgbẹ́ eré sísá àwọn obìnrin ti ilẹ̀ Ethiopia[5]. Ní ọdún 2017, Birhane kópa nínú ìdíje àgbáyé ti eré sísá nínú Marathon ti àwọn obìnrin.