Bisoye Tejuoso
Olóyè Bísóyè Tẹ́júoṣó Jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ìlú Abẹ́òkúta . A bí sínu ẹbí Tẹ́júoṣó ni ilẹ̀ Ẹ̀gbá , tí ó sì jẹ́ olórí àwọn obìnrin ní Abẹ́òkúta àti Iyálóde ní ìlú Ẹ̀gbá pátá pátá.
Bisoye Tejuoso | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1916 Abeokuta |
Aláìsí | 1996 |
Iṣẹ́ | Karakata |
Olólùfẹ́ | Mr J.S. Tejuoso |
Àwọn ọmọ | Oba Adedapo Tejuoso, Karunwi III[1] |
Parent(s) | Chief Karunwi |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "THE RICH AND THE FAMOUS: Old Money vs New Money". The Vanguard. November 26, 2011. http://www.vanguardngr.com/2011/11/the-rich-and-the-famous-old-money-vs-new-money/. Retrieved December 1, 2013.