Bitcoin
Bitcoin | |
---|---|
Prevailing bitcoin logo | |
Denominations | |
Plural | bitcoins |
Symbol | ₿[lower-alpha 1] |
Ticker symbol | BTC, XBT[lower-alpha 2] |
Precision | 10−8 |
Subunits | |
1⁄1000 | millibitcoin |
1⁄100000000 | satoshi[2] |
Development | |
Original author(s) | Satoshi Nakamoto |
White paper | "Bitcoin: A Peer-to-Peer Electronic Cash System" |
Implementation(s) | Bitcoin Core |
Initial release | 0.1.0 / 9 Oṣù Kínní 2009 |
Latest release | 0.18.0 / 2 Oṣù Kàrún 2019[3] |
Development status | Active |
Website | bitcoin.org |
Ledger | |
Ledger start | 3 Oṣù Kínní 2009 |
Timestamping scheme | Proof-of-work (partial hash inversion) |
Hash function | SHA-256 |
Issuance schedule | Decentralized (block reward) Initially ₿50 per block, halved every 210,000 blocks[7][8] |
Block reward | ₿12.5[lower-alpha 3] |
Block time | 10 minutes |
Block explorer | bitaps.com/ |
Circulating supply | ₿17,754,100 (títí di 11 Oṣù Kẹfà 2019[update]) |
Supply limit | ₿21,000,000[4][lower-alpha 4] |
|
Bitcoin (₿, Bítkọìn ní gbólóhùn Yorùbá) jẹ́ owóníná onísíṣeàmìkíkọpamọ irú owó kíkà orí kọ̀mpútà kan. O jẹ́ owóníná orí kọ̀mpútà aláìníolùgba-àrin tí kò ní bánkì agba-àrin rárá tí ẹníkan le fún ẹlòmíràn lórí ẹ̀rọ kọ̀mpútà álásopọ̀ ọ̀rẹ́sọ́rẹ̀ẹ́ láì sí ẹnìkankan ní àrin wọn.[7]
Àwọn kọ̀mpútà alásopọ̀ nodes ló ún ṣe ìjẹ́ẹ̀rí àwọn ìdúnàádúrà tó únṣẹlẹ̀ pẹ̀lú ìṣeàmìkíkọpamọ́ tí wọ́n jẹ́ kíkọ sínú ìwé-àkọọ́lẹ̀ pípínkiri tó hàn sí gbogbo ènìyàn tí à ún pè ní blockchain. Bitcoin jẹ́ dídá sílẹ̀ látọwọ́ ẹnìkan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn ẹníkan tí orúkọ wọn únjẹ́ Satoshi Nakamoto[9] tó sì jẹ́ fífi s'óde gẹ́gẹ́ bíi ìlànà ìṣiṣé kọ̀mpútà atúdìísílẹ̀ ní ọdún 2009.[10] Àwọn bitcoin únjẹ́ dídá gẹ́gẹ́ bi ẹ̀san fún ìgbéṣẹ̀ kọ̀mpútà tí à ùn pè ní mining. Wọ́n ṣe é fi ṣe pasípàrọ̀ fún àwọn owóníná míràn, èso-iṣé àti ìránṣe-iṣẹ́.[11]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Unicode 10.0.0". Unicode Consortium. 20 June 2017. Archived from the original on 20 June 2017. Retrieved 20 June 2017.
- ↑ Jason Mick (12 June 2011). "Cracking the Bitcoin: Digging Into a $131M USD Virtual Currency". Daily Tech. Archived from the original on 20 January 2013. Retrieved 30 September 2012.
- ↑ "Releases - bitcoin/bitcoin". Retrieved 18 May 2019 – via GitHub.
- ↑ Nakamoto; et al. (1 April 2016). "Bitcoin source code - amount constraints". Archived from the original on 1 July 2018.
- ↑ Kettley, Sebastian (21 December 2017). "Bitcoin price: How many bitcoin are there and when will the popular crypto token run out?". Daily Express. Retrieved 6 May 2019.
- ↑ Antonopoulos, Andreas M. (April 2014). Mastering Bitcoin Unlocking Digital Crypto-Currencies. O'Reilly Media. ISBN 978-1-4493-7404-4.
- ↑ 7.0 7.1 "Statement of Jennifer Shasky Calvery, Director Financial Crimes Enforcement Network United States Department of the Treasury Before the United States Senate Committee on Banking:, Housing, and Urban Affairs Subcommittee on National Security and International Trade and Finance Subcommittee on Economic Policy" (PDF). fincen.gov. Financial Crimes Enforcement Network. 19 November 2013. Archived (PDF) from the original on 9 October 2016. Retrieved 1 June 2014.
- ↑ Empson, Rip (28 March 2013). "Bitcoin: How an Unregulated, Decentralized Virtual Currency Just Became a Billion Dollar Market". TechCrunch (AOL inc.). Archived from the original on 9 October 2016. https://techcrunch.com/2013/03/28/bitcoin-how-an-unregulated-decentralized-virtual-currency-just-became-a-billion-dollar-market/. Retrieved 8 October 2016.
- ↑ S., L. (2 November 2015). "Who is Satoshi Nakamoto?". The Economist (The Economist Newspaper Limited). Archived from the original on 21 August 2016. https://www.economist.com/blogs/economist-explains/2015/11/economist-explains-1. Retrieved 23 September 2016.
- ↑ Davis, Joshua (10 October 2011). "The Crypto-Currency: Bitcoin and its mysterious inventor". The New Yorker. Archived from the original on 1 November 2014. Retrieved 31 October 2014.
- ↑ "What is Bitcoin?". CNN Money. Archived from the original on 31 October 2015. http://money.cnn.com/infographic/technology/what-is-bitcoin/. Retrieved 16 November 2015.