Biyi Bandele (Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Ọ̀wàrà Ọdún 1967 ni wọ́n bí i, tí ó sì kú ní ọjọ́ kejè, Oṣù Ògún, Ọdún 2022). Òǹkọ̀wé, àti òṣeré ọmọ Nàìjíríà ni.

Òǹkọ̀wé ọmọ Nàìjíríà Biyi Bandele ní ibi Ìpàtẹ Ìwé Göteborg 2010
Biyi Bandele

Ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ìtàn àròsọ , ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú  The Man Who Came in From the Back of Beyond ní ọdún 1991, bákan náà ni ó kọ àwọn eré onísẹ́ kí ó tó wá gbájúmọ́ fíìmù ṣíṣe. àkọ́já ewé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí  dárí ni Half of a Yellow Sun ní ọdún 2013, tí ó jẹ́ ìwé ìtàn àròsọ Chimamanda Ngozi Adichie

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Yorùbá ni àwọn òbí Bandele, ìlú Kafancha ní Kaduna ni wọ́n bí i sí ní ọdún 1967. Bàbá rẹ̀ Solomon Bandele-Thomas jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀ tí ó ṣe ìpolongo Burma ní ogun àgbáyé kejì nígbà tí Naijiria ṣì wà lábẹ́ àkóso àwọn Bìrìtìkó. Ọdún méjìdínlógún àkọ́kọ́ ìgbésí ayé ni Bándélé lò ni àárín-gbùngbùn àríwá Orílẹ̀èdè kí ó tó wá lọ sí ìlú Èkó, ní ọdún 1987, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré onísẹ́ ni Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ Ilé - Ifẹ̀[1],  [4]ó kọ ìwé ìtàn àròsọ rẹ̀ àkọ́kọ́. "[5]Ó gbégbá orókè nínú idije International Student Playscript ní ọdún 1989 pẹ̀lú iṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n kò tẹ̀ jáde Rain[6] kí ó tó gba àmì ẹ̀yẹ British Council Lagos Award ní ọdún 1990 fún àkójọpọ̀ ewì.  Ó lọ sí Ìlú London ní ọdún 1990, ní ọmọ ọdún méjìlélógún pẹ̀lú ìwé iṣẹ́ ìtàn srosoyrẹ̀ méjì. Wọ́n tẹ àwọn ìwé rẹ̀ jáde, Royal Court Theatre sì fún ní...  Ní ọdún 1992, ó gba àmì ẹ̀yẹ Arts Council of Great Britain Writers Bu Bursar ithenáti tẹ̀síwájú nínú ìwé kíkọ rẹ̀ [8].

IṢẸ́

àtúnṣe

Iṣẹ́ kíkọ Bándélé kó àkóyawọ́ lórí ìtàn àròsọ, tíátà, ìròyìn, tẹlifíṣàn, fíìmù àti rédíò. Ó siṣẹ́ pẹ̀lú Royal Court Theatre àti Iléeṣé Royal Shakespeare, bákan náà ló kọ iṣẹ́ dírámà orí rédíò àti fíìmù fún tẹlifíṣàn. [10]Lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ni: Rain;[11] Marching for Fausa (1993); Resurrections in the Season of the Longest Drought (1994); Two Horsemen (1994) tí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí eré tí ó peregedé jùlọ ní London ní ọdún 1994. Death Catches the Hunter àti Me and the Boys (tí wọ́n tẹ̀ jáde nínú fọ́lọ́mù kìn-ín-ní, ọdún 19951995); àti Oroonoko, Aphda Behn èyí jẹ́ ìṣe àtúndá ìwé náà adaptation [12] ní ọdún 1997, ó ṣe àṣeyọrí Ìwé Chinua Achebe "Things fall apart" gẹ́gẹ́ bí dírámà. Àwọn ìtàn Brixton. Bandele ṣe iṣẹ́ àtúndá ìwé ìtàn àròsọ tara rẹ̀ The Street sí eré ìtàgé,  The Street ní ọdún 1999, tí wọ́n fi lọ́lẹ̀ ni ọdún 2001 premiered in 2001, tí ó sì jáde nínú fọ́lọ́mù kìn-ín-ní àti eré onísẹ́ rẹ̀ Happy Birthday Mister Dekaand was published in  tí ó gbé jáde ní 1999. Bákan náà ni ó ṣe iṣẹ́ àtúndá Lorca Yerma ní ọdún volume with 2001.

Ó siṣẹ́ Olùkọ́ òǹkọ̀wé pẹ̀lú Iléeṣé Tíátà Talawa ni odun 1994 sí 1995, [14],bákan náà ló ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀ǹkọ̀tàn eré onísẹ́ pẹ̀lú Royal National Theatre Studio ní ọdún 1996 [15].  Ọmọ ẹgbẹ́ Wilson ni Kọ́lẹ́jì Churchill, Yunifásítì Cambridge  ní 2001."[16]. Bákan náà ló kópa gẹ́gẹ́ bí Royal Literary Fund Resident Playwright ni Tíátà Bush ní ọdún 2002 sí 2003. [1] [17]. Bandele ti kọ lórí ipa tí iṣẹ́ John Osborne - Back in anger lórí rẹ̀, tí ó rà ní san-án díẹ̀ díẹ̀ ní ojú irin ní Apá Àríwá Nàìjíríà.

Bandele kú ní ìlú Èkó ní ọjọ́ kejè, Oṣù Ògún, Ọdún 2022 ni ọmọ ọdún mẹ́rinléláàdọ́ta. Okùnfà ikú rẹ̀ kò tíì di mímọ̀.

ÀKÓJỌPỌ̀ ÌWÉ

àtúnṣe
  • The Man Who Came in From the Back of Beyond, Bellew, 1991
  • The Sympathetic Undertaker: and Other Dreams, Bellew, 1991
  • Marching for Fausa, Amber Lane Press, 1993
  • Resurrections in the Season of the Longest Drought, Amber Lane Press, 1994
  • Two Horsemen, Amber Lane Press, 1994
  • Death Catches the Hunter/Me and the Boys, Amber Lane Press, 1995
  • Chinua Achebe's Things Fall Apart (adaptation), 1999
  • Aphra Behn's Oroonoko (adaptation), Amber Lane Press, 1999
  • The Street, Picador, 1999
  • Brixton Stories/Happy Birthday, Mister Deka, Methuen, 2001
  • Burma Boy, London: Jonathan Cape, 2007. Published as The King's Rifle in the US and Canada (Harper, 2009).

ÀKÓJỌPỌ̀ FÍÌMÙ

  • Half of a Yellow Sun, 2013
  • Fifty – feature film, 2015
  • Shuga – television series, Season 3 (Shuga Naija), 2013
  • Blood Sisters – Netflix Nigerian Original series, 2022
  • Elesin Oba, The King's Horseman – Ebonylife TV Netflix cop-production, feature film, 2022

ÀMÌ Ẹ̀YẸ

àtúnṣe
  • 1989 – International Student Playscript Competition – Rain
  • 1994 – London New Play Festival – Two Horsemen
  • 1995 – Wingate Scholarship Award
  • 2000 – EMMA (BT Ethnic and Multicultural Media Award) for Best Play – Oroonoko

ÌTỌ́KASÍ

àtúnṣe
  1. ^ a b c d e f Micah L. Issitt, "Bandele, Biyi", Contemporary Black Biography, 2009. Encyclopedia.com. Retrieved 12 October 2015.
  2. ^
  3. ^ a b c James Gibbs, "Bandele, Biyi (1967–)", in Eugene Benson and L. W. Conolly (eds), Encyclopedia of Post-Colonial Literatures in English, Routledge, 2004, p. 96.
  4. ^ a b c Isa Soares and Lauren Said-Moorhouse, "Biyi Bandele: Making movies to tell Africa's real stories", CNN, 4 March 2014
  5. ^ "Biyi Bandele (Nigeria)" Archived 26 May 2015 at the Wayback Machine, Centre For Creative Arts, University of KwaZulu-Natal, 2011.
  6. ^ "Burma Boy (The King's Rifle) by Biyi Bandele", The Complete review.
  7. ^ Tony Gould, Burma Boy, by Biyi Bandele – Reviews, Books Archived 23 October 2007 at the Wayback Machine, The Independent, 29 June 2007
  8. ^ Paul MacInnes, "Biyi Bandele: 'And then we all got typhoid …'", The Guardian, 19 September 2013.
  9. ^ Guy Lodge, "Toronto Film Review: Half of a Yellow Sun", Variety. 17 September 2013.
  10. ^ Karl Quinn, "Director Biyi Bandele cuts the cliches in Half of a Yellow Sun", Sydney Morning Herald, 27 March 2014.
  11. ^ Clayton Dillard, "Half of a Yellow Sun" (review), Slant, 12 May 2014.
  12. ^ "Biyi Bandele's Adaptation of Chimamanda Ngozi Adichie's Half of a Yellow Sun", Aesthetica Short Film Festival.
  13. ^ Davina Hamilton, "'Not Every Nigerian Film Is A Nollywood Movie'", The Voice, 10 October