Black Panther Party (ti a mo si Black Panther Party fún ìdáàbòbò fún ara-ẹni ni igba ti won koko da sile) je egbe oselu fun idagbasoke ati ilosiwaju awon alawo dudu ni orile-ede Amerika larin odun 1960 titi de gbogbo odun 1970.

Àpèjọ Black Panther Party.
Black Panther Party
Ìdásílẹ̀1966 (1966)
Ìtúkác. 1976
Ọ̀rọ̀àbáMarxism-Leninism, Maoism, internationalism, socialism, Communism
Ipò olóṣèlúFar left
Ìbáṣepọ̀ akáríayéAlgeria, Cuba, France
Official colorsBlack, Light Blue

Huey P. Newton ati Bobby Seale ni won da sile ni osu kewa odun 1966 ni Oakland ni Kalifọ́rníà.