Blessing Ogbojionu jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 26, September ni ọdun 1982. Arabinrin naa ṣere fun Pelician Stars gẹgẹbi Ipo forward[1][2][3].

Blessing Igbojionu
Personal information
Ọjọ́ ìbí26 Oṣù Kẹ̀sán 1982 (1982-09-26) (ọmọ ọdún 42)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Playing positionForward
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2004Pelican Stars
National team
2004Nigeria women's national football team0 (?)(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Blessing kopa ninu olympic ọdun 2004 nibi ti o ti jẹ àṣoju team apapọ awọn obinrin bọọlu[4][5]

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://fbref.com/en/players/713bf179/Blessing-Igbojionu
  2. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=313811
  3. https://www.olympedia.org/athletes/108603
  4. https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensolympic/athens2004/teams/1882893
  5. https://www.worldfootball.net/player_summary/blessing-igbojionu/