Blossom Chukwujekwu

Òṣéré orí ìtàgé

Blossom Chukwujekwu jẹ́ òṣèré láti orílé èdè Nàìjíríà , tí ó ṣe akọṣere rẹ̀ ní ọdún 2009. Ní ọdún 2015, ó gba Àmì -ẹye Òṣeré àtìlẹyìn tí ó dára jù lọ ní Africa Magic Viewers Choice Awards. [1]

Blossom Chukwujekwu
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kọkànlá 1983 (1983-11-04) (ọmọ ọdún 41)
Benin City, Edo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaBenson Idahosa University
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́2009-present
Gbajúmọ̀ fún
Olólùfẹ́ Ehinome (nee Akhuemokhan) Chukwujekwu

Ìgbésí ayé rẹ

àtúnṣe

Blossom Chukwujekwu ṣe ìgbéyàwó ìbílè[2] pẹ̀lú Maureen, ní 19 December ọdún 2015 kí wọ́n tó kọ ará wọn lẹ̀ ní september 2019. Lẹ́yìn ọdún mẹta, Blossom fẹ́ Winifred Ehimome (nee Akhuemokhan) tó jẹ́ ọmọ àbúrò oníwàásù, olókìkí àti aláàánú , Chris Oyakhilome

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe