Bnxn
Daniel Etiese Benson (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1997), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Bnxn (tí àwọn ẹlòmìíràn máa ń pè ní Benson) tí wọ́n sì ń pè ní Buju tẹ́lè,[1][2] jẹ́ olórin ilẹ̀ Nàìjíríà.[3]
Daniel Etiese Benson jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Èkó. Ó wá láti ìlú Akwa ibom, ó sì dàgbà pẹ̀lú àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀, ṣụ̀gbọ́n ó kúrò lẹ́yìn ọdún díẹ̀, tí ó sì lọ ń gbé ní Ìpínlẹ̀ Ògùn. 2face Idibia mú Benson wọ ẹgbẹ́ àwọn olórin ti ilẹ̀ Africa lásìkò tí Benson ṣì jẹ́ ọmọ kékeré. Benson fọ ọ́ di mímọ̀ pé Burna Boy ni òun máa ń wò gẹ́gẹ́ bí àwòkọ́ṣẹ fún àwọn orintirẹ̀.[4]
Bnxn gbé orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde, èyí tí ó jẹ́ ti play project, tí àkọ́lé rẹ̀ sì jẹ́ “sorry I’m late” ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù kẹwàá ọdún 2021, lásìkò tí ó tọwọ́ bọ̀wé pèlú T.Y.E/EMPIRE.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Alake, Motolani (2021-11-04). "Mayorkun is shocked that Buju's name is Daniel Benson". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-01.
- ↑ Edeme, Victoria (18 February 2021). "Singer Buju changes stage name to 'BNXN'". The Punch. The Punch Newspaper. Retrieved 18 February 2022.
- ↑ Alake, Motolani (26 May 2021). "Burna Boy, Joeboy, Omah Lay, Buju, Tems emerge as part of the most-streamed artists in the world on Audiomack". Pulse Nigeria. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "INTERVIEW: BNXN". TIRADE WORLD (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-16.
- ↑ Alake, Motolani (28 October 2021). "Buju releases 7-track sophomore EP, 'Sorry I'm Late'". Pulse Nigeria. Retrieved 8 November 2021.