Bode George

Olóṣèlú

Olabode Ibiyinka George je agba oloselu omo bibi ipinle Eko ni apa iwo-oorun orile-ede Naijiria. A bii ni ojo kokanlelogun, osu kokanla odun 1945[1]. O ti figba kan je Gomina ijoba ologun Ipinle Ondo ni odun 1988 si 1990[2]. Titi di asiko yii, Bode George je omo egbe-oselu alatako People Democratic Party[3]

Olabode Ibiyinka George
9th Governor of Ondo State
In office
July 1988 – September 1990
AsíwájúRaji Alagbe Rasaki
Arọ́pòSunday Abiodun Olukoya
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíNovember 21, 1945
Lagos, Lagos State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúMilitary
ItokasiÀtúnṣe

  1. "Bode George". Wikipedia. 2009-11-08. Retrieved 2019-09-17. 
  2. "Night of long knife for Bode George...a news analysis". Vanguard News. 2009-10-26. Retrieved 2019-09-17. 
  3. Published (2015-12-15). "Lagos PDP bashes Agbaje over comments on Bode George". Punch Newspapers. Retrieved 2019-09-17.