Bolot Feray, jẹ eré oníṣe aláwàdà Seychellois ti ọdún 1995 tí Jean-Claude Matombe jẹ́ olùdarí Marie-Therese Choppy sì ṣe àgbéjáde rẹ̀. ògbóǹtarìgì òsèré Alain Belle ni ipa titular tí Charles DeCommarmond, Jenita Furneau, Antonia Gabriel ati Marie Lista kó ipa àtìlẹyìn. O da lori ere kan ati ṣafihan aṣa àti ìṣẹ̀dálẹ̀ awujọ Seychellois.

Bolot Feray
AdaríJean-Claude Matombe
Olùgbékalẹ̀Marie-Therese Choppy
Òǹkọ̀wéMarie-Therese Choppy
Àwọn òṣèréAlain Belle
Charles DeCommarmond
Jenita Furneau
Antonia Gabriel
Marie Lista
OrinConrad Damou
Patrick Morel
Ìyàwòrán sinimáVincent Joseph
Humbert Mellie
OlùpínSBC
Déètì àgbéjáde1995 (Seychelles)
ÀkókòÌṣẹ́jú Márùndínlàádóje
Orílẹ̀-èdèSeychelles
ÈdèFrench

Eré oníṣe náà gba àtúnyẹ̀wò rere àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ eré oníṣe àgbáyé. Eré oníṣe náà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn eré Áfíríkà tí ó dára jùlọ. Geva René ẹni tí ó kọ eré náà ní àkọ́kọ́.

Òṣèré

àtúnṣe
  • Alain Belle bi Bolot Feray
  • Charles DeCommarmond bi Arakunrin Sarl
  • Jenita Furneau bi Mari
  • Antonia Gabriel bi Pierreline
  • Marie Lista bi Poupet

Awọn itọkasi

àtúnṣe