Booker T. Washington
Olóṣèlú
Booker T. Washington | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Booker Taliaferro Washington Oṣù Kẹrin 5, 1856 Hale's Ford, Virginia, U.S. |
Aláìsí | November 14, 1915 Tuskegee, Alabama, U.S. | (ọmọ ọdún 59)
Iṣẹ́ | Educator, Author, and African American Civil Rights Leader |
Signature | |
Booker Taliaferro Washington (April 5, 1856 – November 14, 1915) je oluko, olukowe, afenuso ati olori oloselu ara Amerika. Ohun ni o eni asiwaju lawujo awon omo Afrika Amerika ni Amerika lati 1890 de 1915. Bi asoju togbeyin ninu awon iran olori alawodudu Amerika ti won bi sinu oko-eru, o gbenuso fun ogunlogo awon adulawo ni Guusu ti won ko ni eto idibo nigbana nitori imukuro ominira latowo awon asofin apaguusu alawofunfun.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |