Bookshop House tí wọ́n tún dá pè ní ( CSS Bookshop) ni ó jẹ́ ilé kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní agbègbè Lagos Island tí ó bẹ wà ní Broad street ní òpópónà Ọdúnlámì.[1] Ọ̀gbẹ́ni Godwin and Hopwood Architects ni ó ya àwòrán ilé náà.

Book shop House, Lagos Island

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe