Bose Omolayo (ti a bi ni ọjọ kinni oṣu keji odun 1989) je omo orile-ede Naijiria . O gba ami-eye goolu ni ipele 79 kg ti awọn obinrin ni Idije Igba ooru 2020 ti o waye ni Tokyo, Japan. [1] lẹhinna oṣu die, o gba ami-ẹri goolu ninu iṣẹlẹ rẹ ninu idije Agbaye ti awon akanda eda ni 2021 ti o waye ni Tbilisi, Georgia. [2] [3] Ni ere ije yii, o tun ṣeto igbasilẹ agbaye tuntun ti 144 kg. [4]

Bose Omolayo
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kejì 1989 (1989-02-01) (ọmọ ọdún 35)
Igbuzo, Nigeria
Weight74 kg (163 lb)
Sport
Erẹ́ìdárayáPowerlifting
Event(s)+61 kg
Updated on 11 October 2014.

O dije ninu ipele awọn obinrin ni +61 kg ni ere Agbaye 2014 nibiti o gba ami-ẹri fadaka kan. [5] [6]

Awọn itọkasi

àtúnṣe

Ita ìjápọ

àtúnṣe