Bracket jẹ́ olórin orílè-èdè Nàìjíríà méjì kan, tí wọ́n ń kọ orin afropop àti R&B. Oŕkọ àwọn olórin méjèèjì yìí jẹ́ Obumneme Ali "Smash" àti Nwachukwu Ozioko"Vast".[1][2]

Bracket
Orúkọ àbísọNwachukwu Ozioko
Obumneme Ali
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiVast & Smash
Irú orinR&B, Afropop
InstrumentsVocals
Years active2004–present
LabelsApe Planet
Associated acts

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Babatunde Ologe (27 August 2010). "ASUU Strike Saved Us – Bracket". News Nigeria. Archived from the original on 20 April 2016. https://web.archive.org/web/20160420170402/http://www.news.nigeriang.com/?p=1800. Retrieved 29 July 2015. 
  2. "Bracket: The Yori Yori duo". 9jaHob.com. 6 June 2009. https://9jahob.com/bracket-the-yori-yori-duo. Retrieved 29 July 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]