Chukwuebuka Emmanuel Amuzie (tí wọ́n bí lọ́jọ́ 5, oṣù February ọdún 1996), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Brain Jotter, jẹ́ aláwàdà, òṣèré ayélujára àti ẹlẹ́yinjú-àánú ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria.[1][2]

Brain Jotter
Orúkọ àbísọChukwuebuka Emmanuel Amuzie
Ìbí5 Oṣù Kejì 1996 (1996-02-05) (ọmọ ọdún 28)
Orile Iganmu, Lagos State, Nigeria
Medium
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Genres
IbiìtakùnBrain Jotter on YouTube

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe