Brandon Routh
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Brandon James Routh ( /ˈraʊθ/; tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù Kẹ̀wá ọdún 1979)[1] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ṣeré Superman nínú fíìmù 2006 film Superman Returns, èyí tí ó mú kí ó gbajúmọ̀ káàkiri orílẹ̀ èdè. Ní ọdún 2011, ó ṣeré nínú fíìmù Dylan Dog: Dead of Night. Ó tún kó ipa Daniel Shaw nínú fíìmù NBC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Chuck. Ara àwọn eré míràn tí Routh ti kópa ni Zack and Miri Make a Porno àti Scott Pilgrim vs. the World.
Brandon Routh | |
---|---|
Routh ní GalaxyCon Columbus ní ọdún 2022 | |
Ọjọ́ìbí | Brandon James Routh 9 Oṣù Kẹ̀wá 1979 Des Moines, Iowa, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Iowa (attended) |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1999–present |
Olólùfẹ́ | Courtney Ford (m. 2007) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Signature | |
Ní ọdún 2014, ó kó ipa Ray Palmer / The Atom nínú eré Arrow. Ó tún kó ipa kan náà nínú Arrowverse shared universe: The Flash àti Legends of Tomorrow.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "UPI Almanac for Sunday, Oct. 9, 2020". United Press International. October 9, 2020. https://www.upi.com/Top_News/2020/10/09/UPI-Almanac-for-Friday-Oct-9-2020/1011601996040/. "...actor Brandon Routh in 1979..."