Bright Chimezie tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1960 (1st October 1960) jẹ́ gbajúmọ̀ olórin ìgbà kan ọmọ bíbí Ìgbò lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1] [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Akintomide, Fola (2015-07-09). "Happenings - FLASHBACK: The Originator Of Zigima Sound, Bright Chimezie". 9ja.happenings.com.ng. Archived from the original on 2015-07-09. Retrieved 2020-02-27.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Why I disappeared, Bright Chimezie speaks". Vanguard News. 2010-04-23. Retrieved 2020-02-27.