Brila FM
Brila FM jẹ́ iléṣe igbogunsafefe erẹ idaraya tí wón dá sílè ní ọdún October 1, 2002, Larry Izamoje jẹ́ Oludasile Iléṣe náà tí ó jẹ Iléṣe igbohunasfefe erẹ idaraya àkọ́kọ́ ní orílẹ̀ èdè Nigeria. Brila FM ní iléṣe mẹ́rin ní èkó, Abuja, Onitsha àti Port Harcourt; Iléṣe náà ṣẹṣẹ ṣe awijare ní Kaduna. Ní ọdún 2014 FIFA World Cup wọn yan iléṣe náà gẹ́gẹ́ bí ọkan lára iléṣe mẹ́ta aṣáájú igbohunasfefe partners by Optima Sports Management International.