Broad Street jẹ́ òpópónà kan tí ó wà ní Lagos Island, tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Òpópónà yí jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn pópó tí àwọn ọlọ́jà ti ń taja jùlọ.[1][2]Lára àwọn ilé ìtajà tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ni: Bagatelle restaurant,[3] ilé-ẹ̀kọ́ "Christ Church Cathedral Primary School",[4]ilé-ẹ̀kọ́ Eko Boys High School, ilé-iṣẹ́ Ìwé-ìròyìn Newswatch (Nigeria), àti ilé-ẹ̀kọ́ aládàáni ti St. Mary's Private School.[5] Wọ́n kọ́ "Sẹkitéríátì" síbẹ̀ ní ọdún 1906.[6]

Sign-Post of Broad Street, Lagos, Nigeria

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Reuben K. Udo (1970). "Lagos Metropolitan District". Geographical Regions of Nigeria. University of California Press. https://books.google.com/books?id=AGuri9TP5kgC&pg=PA11. 
  2. State of the World's Cities 2004/2005: Globalization and Urban Culture. UN-HABITAT. 2004. ISBN 978-92-1-131705-3. https://books.google.com/books?id=dxaCfKhlFpsC. 
  3. "Nigeria: Lagos", West Africa (4th ed.), Lonely Planet, 1999, pp. 710+, OL 8314753M 
  4. "Christ Church Cathedral Primary School, Lagos - Lagos Schools Online". lagosschoolsonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-27. Retrieved 2018-11-27. 
  5. "St. Mary's Private School, Broad Street - Lagos Schools Online". www.lagosschoolsonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-27. Retrieved 2018-11-27. 
  6. Nigeria. Bradt Travel Guides. 2008. ISBN 978-1-84162-239-2. https://archive.org/details/nigeria0000will. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

àtúnṣe

Èka:Streets in Lagos