Bryan Okwara tí wọ́n tún mọ̀ sí Ikenna Bryan Okwara (tí wọ́n bí ní 9 November 1985) jẹ́ òṣẹ̀rékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó wá láti ẹ̀yà Igbo. Ó kópa nínú ìdíje kan, tó sì jẹ́ olúborí, tó sì tún gba àkọ́lẹ́ Mr. Nigeria ní ọdún 2007[1][2][3].

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Okundia, Jennifer (17 February 2020). "Mr Nigeria welcomes son with girlfriend". P.M. News. Retrieved 18 March 2021. 
  2. "Ikenna Bryan Okwara - Nigeria". Archived from the original on 7 December 2008. Retrieved 2009-01-30.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "The Handsome Bryan Okwara". Pulse Nigeria. 7 July 2014. Archived from the original on 26 November 2021. Retrieved 18 March 2021. 
  4. "Bryan Okwara". IMDb. Retrieved 2021-12-20.