Bukola Oladipupo (ti won bi ni May 23, 1994) jẹ òṣèrébìnrin ọmọ órílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti o bẹrẹ ere ori-itage re lori MTV Shuga.[1][2][3]

Bukola Oladipupo
Ọjọ́ìbíAdebukola Oladipupo
23 Oṣù Kàrún 1994 (1994-05-23) (ọmọ ọdún 30)
London
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹ̀kọ́Covenant University
Iṣẹ́actress

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́

àtúnṣe

Ilu London ni won bi Oladipupo si ,sugbon ilu Eko ni o ti kàwé.[4] Oladipupo ka eko alakobere re ni Bellina Nursery and Primary School Akoka,Eko. O tun lọ si Ile-iwe giga Babcock ati Caleb International fun eto-ẹkọ girama rẹ. O Kekoo Eto Alaye Isakoso ni Covenant University.[4]

Awọn fiimu

àtúnṣe
  • Òlòtúré[5]
  • Moms At War
  • Juju Stories

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. MTV Shuga https://www.mtvshuga.com/mobile/naija/news/meet-the-cast-adebukola-oladipupo. Retrieved May 22, 2022.  Missing or empty |title= (help)
  2. "Dailytrust News, Sports and Business, Politics". Daily Trust. Retrieved May 22, 2022. 
  3. "Adebukola Oladipupo". World Bank Live. October 29, 2019. Retrieved May 22, 2022. 
  4. 4.0 4.1 "Adebukola Oladipupo Is The Actress All Nigerians Wants To See On The Big Screen In 2022". KOKO TV Nigeria. January 29, 2022. Retrieved May 23, 2022.  Text "Nigeria News & Breaking Naija News" ignored (help)[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. Akinyoade, Akinwale (June 3, 2019). "Òlòtūré: A Journey Into The Underworld of Human Trafficking". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on May 22, 2022. Retrieved May 22, 2022.